60. "Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?”"
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta tiè ní ogúnlúgba. Kí ni wón ti nse àmódù ní ìlorin? Ewúré njé béè.Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kékeré l’òpòló fi ga ju ilè lo. Kì í dowó-o baba kó ní ó di owó omo. Kíni ànfàní-i kètèkètè lára kétékété à-gùn-fesè-wólè? Kíni apárí nwá ní ìsò onígbàjámò? Kíni eléwé-e-gbégbé ntà tí ó nso pé ojà ò tà? Support the show
Published 04/01/23