58. "Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se."
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Ká wí ogún, ká wí ogbòn, “Ng ò fé, ng ò gbà,” lasiwèré fi npèkun òràn. Kàkà kí àgbò ké, àgbò a kú. Kàkà kí bàbá ran omo ní àdá bo oko, oníkálukú a gbé tiè. Kàkà kí iga akàn ó padà sehìn, a kán. Kàkà kí kìnìún se akápò ekùn, olóde a mú ode è se. Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta...
Published 04/15/23