57. "Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé."
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Jéjé leégún àgbà njó. Jòkùmò-ó se bí èlú, aró la bè lówè. Ká ríni lóde ò dàbí-i ká báni délé. Ká ríni sòrò fúnni ò dàbí-i ká sòrò fúnni ká gbà. Ká wí fúnni ká gbó; ká sòrò fúnni ká gbà; ká bèrè ònà lówó èrò tó kù léhìn káyé báa lè yeni. Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta...
Published 04/15/23