56. "Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí."
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: ìwà ní njo oníwà lójú. ìwòn eku nìwòn ite; olongo kì í gbé tìmùtìmù. ìwòsí ní nba ilé àgbà jé. ìyàwó tó na omo obàkan, òrò ló fé gbó. Ibi tí a fi iyò sí ló nsomi sí.Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta...
Published 04/15/23