55. "ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi."
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs:
ìpénpéjú ò ní enini; àgbàlagbà irùngbòn ò se òlòó. Irú aso ò tán nínu àsà. ìrùkèrè kì í yan ifá lódì; oge, dúró o kí mi. ìsánsá ò yo ègún; ìsánsá kì í káwo obè. ìsé ò tibìkan múni; ìyà ò tibìkan je èèyàn; bí o bá rìnrìn òsì, bí o bá ojú ìsé wòlú, igbá-kúgbá ni won ó fi bu omi fún e mu. Support the show