54. "Ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni."
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: ìlu kan ò tó ègùn jo; bí a bá lù fún un a máa lu àyà. Iná njó ògiri ò sá; ó wá ngbá geere geere sómi. Inú burúkú làgbà nní, àgbà kì í ní ojú burúkú. Ipa ogbé ní nsàn; ipa ohùn kì í sàn. ìpàkó onípàkó là nrí; enieléni ní nrí teni. Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta...
Published 04/15/23