53. "Ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó."
Listen now
Description
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: ìjàlo ò lè gbé òkúta. ìjokòó eni ní múni da ewé èko nù. ìjoba npè ó, o ní ò nmu gààrí lówó; ta ní ni ó, ta ní ni omi tí o fi nmu gààrí? ilé-ni-mo-wà kì í jèbi ejó. ilé kì í jó kí baálé ilé tàkakà. Ilé kì í jó kí oorun kun ojú.  Support the show
More Episodes
In this episode, host Bidemi Ologunde analyzed the following Yoruba proverbs: Kí ni ìbá mú igúnugún dé òdò-o onídìrí? Kí ni ó ya àpón lórí tó fisu síná tó nsúfèé pé “bí a ti nse ni inú mbí won?” Kí ni onígbá nse tí aláwo ò lè se? Kí ni orí nse tí èjìká ò lè se? èjìká ru erù ó gba òódúnrún; orí ta...
Published 04/15/23